Ẹgbọn oloogbe, Adegoke Olugbade, lo sọ eyi fun BBC . Olugbade ni awọn mọlẹbi ko gbọ ohunkohun lati ọdọ mọlẹbi Adedoyin saaju idajọ ile ẹjọ Ko-tẹmi-lọrun niluu Akure.