Ọpọlọpọ obinrin ni ko mọ ohun pupọ nipa oju abẹ wọn eleyii ti awọn oloyinbo n pe ni Vagina. Ni aye ode oni, awọn obinrin miran ko mọ nipa iyatọ to n de ba oju ara ni oṣooṣu, imọtoto ati ẹya ara naa, ...